Yo si pemi ni irawo re,
Emio si pe ni osupa mi,
Otipe ti mo tije oludanwo,
Ni toto ife re kami laya,
Emio si sare koja ilu yi,
Losi ilu aye ati oro,
Pelu ikowe kekere yi ni owo mi,
Ojo rere imi lema waye,
Emio si ko si gbogbo ogiri,
Pelu ikowe kekere yi lowo mi,
Oro ife wa ti kole e daru,
Si gbogbo etii ara aye kan gbo,
Ni toto yosi pemi ni irawo re,
Nitori ojo rere le ma waye,
Lati fo oro ife inure jade,
Lati okan re to ma sese bi adaba,